Mo gbo Anago (Yoruba)

Spring chicken character with bling, handbag. Fun hen.
Middle age!

Too, gbogbo omo OOdua patapata nile loko, leyin odi ati nibikibi ti e ba ti n gbo mi. Mo kiyin teshotesho oo. Mo ki yin tologun tologun. Ojiji lo yo simi lokan wipe, nigba ti awa ta lede nsa lo fun ede wa, ti oju n ti wa ati so ede na ti awon Ashiwaju wa fi le wa lowo. Ko bojumu nigbana lati fi esun kan awon eloomiran wipe won n fi oju tembelu ede, asha ati ishe nigbati ko jo awa oninkan gan loju. Bonigba wa se pe igba re. Awon to gbon juwalo nijjoonihin ana, won ti kose siwa lori lati foju tembelu ede tiwa gangan. Beeyan bawa lo yoruba kawe, kowe tabi ko leta paapa ko fi gbe eto kale lori ero radio tabi television, awon egbe re n won koo foju paa e re bi eni wipe alaimokan lonitohun. Idi ree ti a o tun fi ji eto loju oorun. I yen ni wipe  a o pada sori eto yi ti o tumo si wipe mo gbo Yooba.

Lori eto naa, igba ra eni ni iyanju ni o, paapa fun awon odo wa gbogbo kaakiri origun mererin agbanla aye. Ki ma ba opo lo si ile olooro, e ma ye wa wo nihahin fun eto naa “MO GBO ANAGO / MO GBO YOOBA”. A o maa reti awon ojogbon ni ile Yooba, awon omoran ti n mo oyun igbin ninu ikaraun re lati maa lawa loye lori awon koko oro to she pataki dede. A ku oju lona.http://yinkasulaimanruthstudio/MO GBO YORUBA

Spring chicken character with bling, handbag. Fun hen.

Leave a Reply

Fill in your details below or click an icon to log in:

WordPress.com Logo

You are commenting using your WordPress.com account. Log Out /  Change )

Twitter picture

You are commenting using your Twitter account. Log Out /  Change )

Facebook photo

You are commenting using your Facebook account. Log Out /  Change )

Connecting to %s